Olubusayo Oladipo – Wo Ki O R’iye Lyrics & Mp3 Download

Olubusayo Oladipo - Wo Ki O R’iye Lyrics & Mp3 Download

Chorus:

Wo o ki o r’iye
Wo Jesu ki o r’iye
Wo o ki o r’iye
Wo Jesu ko d’asegun
Verse 1:
Iku oro re lori igi
L’o fun mi ni iye
O so mi d’omo
Mo r’iye gba ninu Oluwa
Ide mi ja o mo yege
Tori mo wo o mo r’iye
(ore mi)
Solo 2:
Okunkun d’opin o
Ija d’opin
Imole mi tan iye
Iye mi de,
Kristi ninu mi
Ireti ogo mi
Orin halelujah ni mo nko
Olurapada lo ra mi pada
Mo dalayo mo sorire
Olurapada lo ra mi pada
Mo r’iye gba, Mo j’asegun lo
I’ve a message from the Lord,
Hallelujah!
The message unto you I’ll give
‘Tis recorded in His word,
Hallelujah!
It is only that you “look and live”
Look and live my brother live
Look to Jesus now and live
‘Tis recorded in His word,
Hallelujah!
It is only that you look and live
Wo k’o ye, Arakunrin
Wo Jesu ki o si ye
A ko sinu oro re
Aleluya
P’eni t’o ba wo Jesu y’o ye

DOWNLOAD MP3 NOW!

“Wo Ki O R’iye” Lyrics & Mp3 Download by Olubusayo Oladipo

Join Our Telegram Channel

Leave a Reply

Your email address will not be published.

Related Articles

Back to top button
eskort mersineskort mersin